Posts

OLUGBOHUN ORANGUN

#OLUGBOHUN Oga aye kan, eja ojiji aye kan, alakan aye kan, akeeke aye kan, opolo aye kan, alangba aye kan, ao ko gbogbo re sinu iwo maalu tokenu, ao fi ogogoro ojuda po ose dudu, ao kole won lorii, ao gbe ile sidi igi ogede, ao gbe iseyii sii, ao da ikoko boo monle, ao sare kuro nibe, Toriwipe tabape nibe ara lesan, osilewu pupo, tobape ojo keje tase agbara yii, ao wa jepe, (Aso tokangun si ara egungun lo nje bee), ao mu dani, ao wa lowu olugbohun yii, ao fi aso yen boo lorii, ao siba pin ohun wipe, Nkan bayibayi ni mofe kio maase funmi, ao gbe sinu iyara aiwo kan, ao wa fila(cap)alaran aye atijo, ao fi bo olugbohun yen lori, ao wafi ikoko yen boo pada, LILORE Ao ma pe oruko re tabatifeelo, pelu nkan tafee ran, AKIYESI - Tia banlo si ibikan tia bafilede fila yen, gbogbo nkan tabaso pata lojo yen Odi ase

IWE IDA AKONI

Image
  PDF    N5000   hard copy 10,000    for password => call : 08105297751 Download Here

IWE ASIRI VOL. 2

Image
PDF    N5000   hard copy  9,000   for password - => call : 08105297751 Download Here

IWE ASIRI VOL. 1

Image
  PDF    N5000   hard copy  7,000     for password => call : 08105297751 Download Here

OGUN TI ONISE OWO FI RISE GBA

Ori Okere kan Akere kan ibose Alike Adie Ewe Gbegbe 5. Ose dudu Ao jo gbogbo re papo leekanna pelu Odindin ataare kan ao lo daadaa ao po mo ose dudu, ao ma we ni owuro kutukutu ki orun to yo pelu OFORE RE.... Enu ni Okere nfi pe olode ninu igbo.. Omo araye ewa pe emi lagbaja omo lagbaja fun ise mi Enu ni Akere nfi pe omi we.. Mom araye ema pe emi lagbaja fun ise ti mo nse Ewe Gbegbe loni ki e ma gbe Ise Kekere owo nla wa fun emi Lagbaja omo Lagbaja Nitoripe Adiye ki wale ki o mari ohun ti yio je.... Ao ma se adura to ba wuwa si ao ma pe ofo yen ti a nba we tested gidi ni

ORUKA OLUGBOHUN NLA

AO WA EWE INA ATI ESINSIN EWE AHARAGBA EWE JEMINIHO EWE WEREPEPE .OPOLO NLA KAN AOGUN EWE ATI OPOLO YEN MO EWE NA PELU ODIDI ATARE AJA KAN. AOWA FI OSE DUDU KO PELU ITOO WEERE AO KO OSE NA SINU IKE KAN NA AO WA LO WA OPOLO MIRAN ATI OGA AO KO OSE YEN DIE SINU AGOGO IDE KAN AO JU ORUKA IRIN DUDU OYEKOYE KAN SI ORI OSE INU AGOGO IDE YEN AO WA PA OGA AODA EJE RE SI AO TUN PA OPOLO YEN NA AO DA EJE RE SI AOKO OSE TOKU LE AO WA FI ASO PUPA WE DADA LORI AO RIMO ORISARE TIWON KO TIRE RARA FUN OJO MESAN LEHIN OJO KESAN AO GBE AGOGO YEN AOFI IGI KO OSE RE AO FI IGI KO ORUKA NA SIBI KAN AO WA KO OSE YEN AOLOFIWE LOJO META KATO LELO ISE YI. AOKO ORUKA YEN SINU APE AOKO OSE DIE SI AOWAJO PO .ODILILO TABA TI WE OSE YEN NA LAOTO MAKI BOWO OO. EWORE ATI AKIYESI... AOBUDO FI ORUKA YI KANYAN O.EJE ENI YEN YIO GBE NI. ORUKA NA KIYAN TIKO WE OSE YEN LARA. OSISE APASE NA. LILO FUN OLUGBOHUN ATI APASE Lilore....aokibowo aofi ahan kan leemeta fi soro... Lilore ..fun apase.... Aofi akan leekan per...

OLUGBOHUN NLA EPE ATI ADURA

MOFE FI ASIRI KAN SILE ASIRI TODE DAJU DADA NI TESTED AND CONFIRM NI TI MONLO NIBI KOYE KIFI ASIRI YI SILE AMO EJE KAFI SUURU GBE NKAN YI OOOOO KOSI WIPE OSE KO SISE RARA OOO IWO TI OBA SE ASIRI TI OBA BA NBE SOPE OGUN TIKODAJU NI BABA YI MA FI SILE MONLO ELEYI LOWO OKEERE LOJU AMO OTA LENU WEWE TIBA SE FUN OOO MAGBA EGBERE ADOTA LOWO RE AMO HMMMMM EJEKAFI SILE #OLUGBOHUN__GIDI LELEYI___OOO___TOHUN____YARA___BI__ASA__ EGBO AKESE PUPA OOJO EGBO AKEREJUPON EGBO OGBO OOJO AOGUN METETA PAPO MO OSE AGANYIN DUDU. EO WA MU AYE OGA IBILE KAN SINU AGOGO IDE TI YIO KO ENU SOKE EO KO OSE LE LORI EO WA FI ASO PUPA BO LORI EO WA WE AKISA ASO KAN MO EOLORIMO MOLE SI OJU ONA TI ESE NGBA DADA FUN OJO MEJE. LEYIN OJO KEJE EOLO WO EO GBE PAMO SI IBI KAN TO SAVE DADA LILORE ----- ------ --------- ------------ LILORE RE_____________ __________ Is loading __EO YASI LEEMETA EOSO NKAN TEFE SI OPARI___________ ______________ DIE LARA AWON ASIRI TI NBE NINU IWE ASIRI MEJEJI__ ...