OLUGBOHUN ORANGUN

#OLUGBOHUN Oga aye kan, eja ojiji aye kan, alakan aye kan, akeeke aye kan, opolo aye kan, alangba aye kan, ao ko gbogbo re sinu iwo maalu tokenu, ao fi ogogoro ojuda po ose dudu, ao kole won lorii, ao gbe ile sidi igi ogede, ao gbe iseyii sii, ao da ikoko boo monle, ao sare kuro nibe, Toriwipe tabape nibe ara lesan, osilewu pupo, tobape ojo keje tase agbara yii, ao wa jepe, (Aso tokangun si ara egungun lo nje bee), ao mu dani, ao wa lowu olugbohun yii, ao fi aso yen boo lorii, ao siba pin ohun wipe, Nkan bayibayi ni mofe kio maase funmi, ao gbe sinu iyara aiwo kan, ao wa fila(cap)alaran aye atijo, ao fi bo olugbohun yen lori, ao wafi ikoko yen boo pada, LILORE Ao ma pe oruko re tabatifeelo, pelu nkan tafee ran, AKIYESI - Tia banlo si ibikan tia bafilede fila yen, gbogbo nkan tabaso pata lojo yen Odi ase

Comments

  1. Replies
    1. Thank you sir,God will bless you

      Delete
  2. E se gan ni sir , sugbon mofe bere ibere meji kan lowoyin akoko ninu ibere mi nipe eniti abape nidi ogede ti afegbe iseyi si di ojo keje ara yio San o ni lewu ... Mowafe bere pe se aletigbe iho na sile ki atogbe olugbohun yi de ibe ....
    Ibere keji:-ni ojo keje ta mu aso egungun yi de idire ni ao so ni oruko tobawuwa ? Atipe fila aranyi tafibo yi ale made lekokan tabafe... Se lesekese ni ohunti moba so yio sele nibi ti Ade fila naa lo?

    ReplyDelete
  3. Thanks so much sir 💗

    ReplyDelete
  4. Open in folorun ejo bawo la nse lo ise Yi sir

    ReplyDelete
  5. Ejowo ero re sir

    ReplyDelete

Post a Comment

Popular posts from this blog

OLUGBOHUN NLA EPE ATI ADURA

OGUN ORUKA AWAMARIDI TESO TODAJU DADA

OGUN TI ONISE OWO FI RISE GBA