AWAMARIDI TI OGUN KONI HANWA TO SISE AJEOGUN NA

MOFI ASIKO YI KI BABA MI ORE MI ATATA AKOJUAYE FUN RARA RE AJANAKU ILU COTONU LOHUN MOJUBA OOOOO MOKI GBOGBO OMO EGBE PATAPATA PELU AWON ADM INU YARA YI NA OOOOO SUURU LOGBA JEJE LAYE KISE GIRIGIRI OOOO EMI DR ABANISE FI YEYIN WIPE OGUN TI NBE TO NJE BIDAN MOFI OLORUN BURA ISE YI DAJU GAN TI MOTI TESTED RE TODE SISE DADA... MODE MODE MODE MODE BI MOSE NDE ..OWO MI HAI LATIJO YI NI OOOO LEOFI RI OWO MI FUN OMO EGBE TOFE GBA IWE RE LARIN ILORIN MAFI RANSE SI LOWURO OLA OOO KOMABINU MODE MODE OOOOO EYINI ASIRI AGBARA 2* TOLAGBA TODE SISE DADA... TIWON BA NAWA LOGUN ABI ORUKA KONI SISE BEE NANI ARA ENI NA KONIGBADUN FUN OJO MEJE GBAKO TODAJU DADA .. TWO BLUS NISEYI OSISE AJEOGUN NA OOOO AO WA ODIDI OGA OOYE KAN AOGE APA RE MEJEJI ATI ESE RE MEJEJI SI OTOTO .. SISERE ... AOLO LO OWO OTUN MO EYO ATARE MEJE PELU EWE KUJEKUJE AOFI SINGBERE ORUN OWO OTUN YIPO AOLO OWO OSI MO EYO ATARE MEJE PELU EWE KUJEKUJE DIE NA AOFI SINGBERE OWO OSI ROUND NA.. AOLO ESE OSI MO EYO ATARE MEJE PELU EWE NA .. AOFI SI ESE OSI YIPO NA AOSE ESE OTUN NA BEE AOFI SINGBERE ORUN ESE OTUN WA NA BEEE ISE YI LAGBARA GAN OOO GBIYANJU RE

Comments

Post a Comment

Popular posts from this blog

OLUGBOHUN NLA EPE ATI ADURA

OGUN ORUKA AWAMARIDI TESO TODAJU DADA

OGUN TI ONISE OWO FI RISE GBA