OGUN OLUGBOHUN ELEGERE AKO


#OLUGBOHUN___ELEGERE___AKO___TI___ALE___RAN___NISE___OHUN KOHUN____ALEFI___WO___ILE___ALE__FI PASE___OJO___ALE___LO__FUN___OHUN___KOHUN___OSISE___ALL___COUNTRY____PATAPATA___
100%%%%%
%%%%
EROJARE ...+++
.....
........
OJU ORO OOJO
OSIBATA OOJO
EWE EMILE
OSE DUDU
IWO MALU META NLA NLA ..
ASO PUPA TOFE DADA ...
YEPE AMO ABI YEPE IKAN
ADIN EYAN
ATI EPO PUPA
OGA AYE NLA META
OPOLO OOYE META
AKO ALANGBA OOYE META

SISERE..+++++
........100%
.......
OJU ORO OOJO OSITABATA OOJO TI YIO PO DADAD NI PELU EWE EMILE AOGUN PAPO MO OLUBI OMO IKOKO PAPO MO OSE DUDU AOKO OSE NA SIBI KAN NA ...
.....
AO WA LO WA YEPE AMO KOPO DADA ABI YEPE ILE IKAN AO PO EPO PUPA ATI ADIN DUDU PO YEPE NA DADA ....LEHIN NA AO WA YARA KAN TIKO SI ERU KANKAN NBE RARA AOKUN YARA NA NI ODA WHITE ... AO WA MO YEPE SINU YARA NA ROGODO ...

AO WA MU IWO MALU NLA KAN AOJU OPOLO KAN SI NINU PELU OGA ATI ALANGBA AKO KAN AO WA KO OSE YE LE DIE LORI ...
AOMU IWO KEJI AOJU OPOLO OOYE KAN SI OGA OYE KAN SI ALAMU AKO OIYE KAN SI AOKO OSE YEN LE DIE NA
AOTU MU IWO KETA AOKO OGA OPOLO ALAMU AKO SI AOKO OSE TOBA KUSI LORI ..
........
AO WA PA AWON IWO NLA METETA YI PAPO AOFI ASO PUPA YI GBOGBO LARA ..AMO EMA JE KOBO OJU RE OOOOO

EO WA KI OLUGBOHUN EDIDI YI ..AOKI IDI RE BO INU YEPE YI NINU YARA NA ..TI YIO DURO SOKO ....TI ENU RE YIO WA LOKE NI OOOOO
EO MA DA ASO PUPA BO OLUGBOHUN NA LORI AMO TEBA FE LO EOKA ASO LORI RE...
..,....

IGBAKUGBA TAFE LO ISE YI ...HMMMM
AOWO INU YARA NA...
ISE YI LAGBARA...

HMMMM
LILORE....
LATI FISE OHUN KOHUN....
....

OYA ECOMMENT WIPE OPE NI FUN ELEDUMARE ...

Comments

Post a Comment

Popular posts from this blog

OLUGBOHUN NLA EPE ATI ADURA

OGUN ORUKA AWAMARIDI TESO TODAJU DADA

OGUN TI ONISE OWO FI RISE GBA