ORUKA AGBARA TI ABAFI GBAYAN ENI YIO GANPA BI ERE NI

Ogunda ogun todaju lati owo emi dr abanise D R Abanise AgbomolaAbominate mofi asiko yi kiyin wipe eku ori re..... Efiokan baba dada nipa ise yi momo wipe dr Agbomola AkojuayeAkojuaye yio soro si ise akoja ti mofe fi sile amo shaaaa nkan akoya gidi ni...... ORUKA OJUDA TIA BA GBA EYAN ENI NA INA YIO DAHUN LARA EE YIO GANPA LESEKESE LOJUKAN IBI TOWA...... TESTED OKAY NI... EFI OKAN BALE DADA NIPA ISE.... KOSI OSHEY KOSISE RARA OOOO..... Ise na lobayi.... Eja ojiji meji ooye Ewe ina pupa ati funfun gbigbe abi tutu Ewe esinsin gbigbe abi tutu Ewe oyin Ewe werepe tutu or gbigbe Osan wewe meta Ose dudu abi aganyin Aogun ewe yi po dada pelu Eja ojiji kan pelu osan wewe ati ose dudu Efi okan bale ise todaju dada tested okay by dr agbomola abanise ni eleyi ooooo Suuru di owo yin oooooooooooo Aowa ikoko dudu kan aoko oruka tele aowa ko nkan tagun yen le Ao wa gbe eja toku si aodepa fun iseju marun pere... Aowa si ikoko na aogbe eja yen aolo seje pelu epo ati iyo aoje Aode ikoko yen pada nitire.. Aolo rimo si eyin ilu fun ojo meje leyin na aowa gbe..... Aosi aoko ose yen ninu aowa fi igi ko oruka na aowa lofi ose na we kato le di oruka yen mu....... Awon toba felo oruka na yio we ose na leekan Ero re...... Aomu ose di sinu omi ike ragoliz kan aoda omi si.. Aolu ragolis na lori cover..... Ao ma wonsi eni na lara toba ti ganpa.... Eni toba je eja yen ni oruka yen yio pe lowore ju awon tofi ose we lo Oya more comment... Wipe Olorun oseun..... .

Comments

  1. Gbenga Owolabi OgunsanwoAugust 15, 2019 at 6:41 PM

    Oodua are we awake now? The late Saga my mentor, Chief Obafemi Awolowo said it. To baya aja fun rawa. It is a reality now? But let us first solve the geed in Youruba Kingdom to exploit all Baba God has given us to the glory of Yoruba, the Oaduwas GREED, AND LOVE FOR MONEY. We have it all to greatness in all endowment to ECONOMIC POWER. Ooduwa a gbewa o.
    I said we have it all, rich land, Ocean, rivers, even streams, human power in all aspects of life to greater developopment. and so on. But what have we done with them to greater and sustainable development in ECONOMIC POWER to prosperity? We have it all, These are assets untapped and our people are suffering and dying, in the midst of Gods blessing.We have it all to economic advancement to economic power, but for GREED. Our people loves money and killing great initiatives to economic dependence to economic power. We need to look into this EVIL staring us in the face.

    Gbenga Owolabi Ogunsanwo
    goasuk2002@yahoo.com
    goasuk2002@yayoo.com.

    ReplyDelete

Post a Comment

Popular posts from this blog

OLUGBOHUN NLA EPE ATI ADURA

OGUN ORUKA AWAMARIDI TESO TODAJU DADA

OGUN TI ONISE OWO FI RISE GBA