OGUN ORUKA AWAMARIDI TESO TODAJU DADA


ORUKA YI LAGBA GAN OOOOOO
ORUKA YI AWON AGBA IGBAYEN NLO LATI DE FI DABO BO ARAWON NIPA IYAWO WON.ITORI OPOLOPO IYAWO LO NIFE SI AGBERE GAN NIGBAYEN .AMO LOODE OONI ..KOSI NKAN TOKAN OKUNRIN MI TI IYAWO WON ABI OMO WON OBINRIN BA NYA AGBERE ....
#ORUKA_AWAMARIDI_
YI DARA PUPO GAN LATI NI LOWO FUN AWA OKINRIN TI AKONIFE SI KI IYAWO MA YALE NITA ABI OMO WA MA DOKO KAKIRI ...
EMI DR ABANISE NA NI MIOKI SORO KOMA RIBE OOOOO
....
#ISE_ORUKA_NA_
TI IYAWO WA BA NJADE TABA FI ORUKA YI GBA NIDI HAAAAAAAA...
INA NI KOMO OJU ENI DA OOO
...... .....
ABI KOJE OMO WA OBINRIN LAFI GBA NIDI NIGBA TO HUNLO ..
TI WON BA FE SUMO OKUNRIN KO KUNRIN ..WALAHI TALAHI MOFI ISE YI BURA GIDI GAN..
....
...NKAN OMO KUNRIN NA KONI GBERI RARA OOOO
AMO TI OKUNRIN BAFE SUMO OBINRIN OKO RE YIO GBERI AMO IYAWO WA ABI OMO WA TI ADE TIFI ORUKA NA GBAWON ...HMMM
OKO OKUNRIN KONI GBERI RARA ...OOO
.....
#EROJA_ISE_NA_
EWE AMUNIMUYE
EWE INA
EWA KAKURE DIE
ORUKA OJE KAN
...
.....
#SISERE_
AOLO AWON NKAN YI PAPO ..AOKO SINU IKARAHUN IGBIN KAN ABI INU IKE KAN AORE ORUKA NA SINU RE FUN OJO MEJE GBAKO LEHIN OJO KEJE AOYO AOSA SIBI TI KONIRIN ORUN RARA ...

.....
#LILORE_
AOKIBOWO FI GBA OBINRIN NA NIDI
MAFI SEKA OOOOO
OLORUN NBE OOOO
...USE IT TO PROTECT YOUR SELF WITH YOUR OWN WIFE OR DAUGHTER ...
......
#ERO_RE_
ITORI TI ABA SE LO ERO RE ..HAAAA
OKO TIWA NA KONI GBERI LATI BA ENI NA SUN OOO
...

OYA COMMENT FUN #ERO_RE_

Comments

  1. Replies
    1. e jowo kini ero ogun yi.

      Delete
    2. Baba,agbo ato o,mo nife si ise Yi,mo Fe ero re

      Delete
  2. Replies
    1. Ese pupo baba, Loni ero re sir

      Delete
    2. Mo ba Ogun Yi pade mo si nife si,agbo ato o,ewe a maa je o,kini ero ise Yi baba.

      Delete
  3. E se baba olodumare ko ni ko idi ayinimose si yin. E jowo ki ni ero re

    ReplyDelete
  4. Baba edakun e fun wa lerore sir

    ReplyDelete
  5. Baba E seun fun Ogun yi
    Ewe a ma je fun yin O.
    E jowo kini Ero re ?

    ReplyDelete
  6. Yo maju yinse ejo Sir ki ni ero use yi

    ReplyDelete
  7. Hmmmmm you will never know sorrow sir. Ẹjọ sir kini ẹrọ re

    ReplyDelete
  8. Amajuuyin se ooEjoo mini erore

    ReplyDelete
  9. This comment has been removed by the author.

    ReplyDelete
  10. É seun gan sir, ẹrọ rẹ ni mofe

    ReplyDelete
  11. Thank u sir u ar d best among d rest sir wat is d ero

    ReplyDelete
  12. Baba kini ero ejowo,eseun gaani

    ReplyDelete
  13. Baba efi ero ise na sile funwa nitoripe iyawomi n yan ale

    ReplyDelete
  14. Thanks you sir ejowo baba eroeehunko

    ReplyDelete
  15. Bi a ba fi agbo feegun NSE la jowo okun re sile, e jowo efunwa lero re.

    ReplyDelete
  16. E seun adupe Sir. E jowo e fun mi lero re sori email mi wollytoy@gmail.com.

    ReplyDelete
  17. Baba ẹ dá kún ẹ fún mi ní ẹ̀dọ̀ rẹ̀

    ReplyDelete
    Replies
    1. Ejowo,baba nje obinrin le lo fun omo re?Omo mi ti Fe fi infection pa mi

      Delete
  18. Moni ise yi lowo tio sipe pelu ero re, 07033229262

    ReplyDelete
  19. Ewe oni sun oko, adura a gba

    ReplyDelete
  20. Baba ejo kinni ẹrọ rẹ

    ReplyDelete
  21. Eweamajeo egbo amafowun ajinde Ara amajeo jawesola lokinyio

    ReplyDelete
  22. ESE pupo ewe ama je o

    ReplyDelete
  23. Baba e jowo kini ero re? Ajinde ara ma ma je oo

    ReplyDelete
  24. Eseun pupo olohun a ma fun yin se ooooo amin

    ReplyDelete
  25. Olohun yoo je ki ari yin pe o

    ReplyDelete
  26. Baba mi thanks sir

    ReplyDelete
  27. É seun sir. Ajinde ara a ma jé, sir.

    ReplyDelete
  28. Agbo ato ewe amajo esepupo baba edakun ki ni ero re

    ReplyDelete
  29. Aki babawa ti won fii iseyi sile emi naa nii iseyi mosi nii erore

    ReplyDelete
  30. Thanks sir ejo kini ero re I need it please

    ReplyDelete
  31. Thanks sir please I need it sir
    You can send it here 09067238746

    ReplyDelete
  32. Baba ejo efuwa ni ero re, ejo sir tiyin nan onibaje ooo

    ReplyDelete
  33. Mo ni ise Yi,lowo mo si mo ero re,mo ni awon iwe baba Yi lowo ati orisirisi ise nlanla Miran pe mi 09061636069

    ReplyDelete

Post a Comment

Popular posts from this blog

OLUGBOHUN NLA EPE ATI ADURA

OGUN TI ONISE OWO FI RISE GBA