OSHO IBANTE MUSA

.......BY DR ABANISE..AGBOMOLA.. ...TESTED OKAY NI.... ....100%... .... Eowa obi funfun1, ao gesi ona igbalekan, obi pupa 1 , ao gesi ona igbalekan, eyo atare igbalekan. Ewe owu akese , owo paper to tobi ni inu wa, ao wa jo ako alamu kan pelu abo alamu kan , ao jopo. Ao gbe okuta Ti anfi nlo kan, sinu iyara wa, ao fi gun awon nkan akoko yen mo ose dudu , ao wa fi etu Ti ajo yen fite odu Ifa merindilogun , ao pe ofore si , ao da sinu ose na , ao wa fi po ose na, ao tun fi eje akuko Adie kan fipo ose na, pelu eje eyele funfun kan ao fi po ose na,ao wa fi eyele yi fi se ipese sori ita Meta, ao si tun gbodo je ninu akuko adie Ti apa yi..mewo ni... Ao wa ko ose yi sinu igba olomori , ao gbe ose na sinu apoti iroko, ao wa ma fiwe pelu ofore, ao ma we ose yi ni dede agogo mejila oru Ti enikankan kogbodo riwa OFORE.... ........ ...... oni bante Musa 3x, inu ofin ni mowa yioooo, ki ewa yomi ninu ofin yi loni 3x, eni toyomi ninu ofin ore lofi semi 3x, ewa fi ore aje fisemi loni 3x, ako alangba ki npa ohun abo da 3x, abo alangba ki npa ohun ako da 3x, ki awon omo araiye mapa ohun mi da 3x, Ti akese ni nse lawujo owu 3x, temi ni komase lawujo awon omo araiye 3x, larin obi pupa laari funfun 3x, larin obi funfun laari pupa 3x, atare ki ko ile tie koma kun 3x, olodu merindilogun ki nse nkan tie lete 3x, ao wa da aniyan si ao fi po ose yi, ao tun pe ohun lasiko Ti aba nwe aje ooooo ogunluso.... Tested ni oo

Comments

  1. Any repercussions? If there is, let us know. Your effort is to bless people. Therefore, there is the need to give notice of any taboo or repercussions of this great work. But if there is none, bravo to u sir. Awo ki awo o!

    ReplyDelete
  2. Tested ni ise yi....thank you for your good will

    ReplyDelete

Post a Comment

Popular posts from this blog

OLUGBOHUN NLA EPE ATI ADURA

OGUN ORUKA AWAMARIDI TESO TODAJU DADA

OGUN TI ONISE OWO FI RISE GBA