OSO IMULE ELEIYE NLA
EKU ODUNDUN ONI...MOSESE DE LATI ABEOKUTA BAYI NI OOOO...EGBAYI WO KEFI SODUN TUNTUN ..ODIDANDAN EORI OWO NA ...ITORI OPOLOPO AWON ENIYAN NI YIO TI GBAWI NKAN ABI ..KOMASI OWO LOWO WON ....
.....
....
IMULE
Apa osi aguntan, a o fi tele ape tuntun, eku asin merindinlogun, oga merindinlogun, opolo merindinlogun, opolopo eso ego/eso ori langbodo, ewe aluki, odidi atare merindinlogun, a o jo, a o te osa meji le, a o pe gbolohun si, a o ma fi eko tutu lo.
Ameniye. Afoniye. Iya toboje. Iya tobosu. Iyami nisokun. Iyami nisude. Iyami olominimini-niye.
Eyin mejeje ni e pa de Orunmila lojo ojo si ti e ba Orunmila de ootu- fe. Nigbati e de ootu-fe tan, awon ara ootu-fe ni awon yoo ka eewo ilu awon fun yin o. Won ni won kii ka ila ejio, won ni won kii ro dede ni mosun, won ni won kii fe omo ootu-fe je bi ewe.
Orunmila ni se e to gbo, won ni awon ti gbo. Orunmila ni se e ti gba, won ni awon to gba. Nigbati o di ojo keji Orunmila gbe apo abira re o se awo lo si ile ado. Nigbati o de ile ado tan, gbogbo won ka ila ejio, won ro dede ni mosun, won to si ehinkule orun, won fe omo olufe je bi ewe. Awon ara ootu-fe ranse si Orunmila ni ile ado, won ka gbogbo ohun ti awon alejo re se. Ni Orunmila ba yo ida, o ni oni dandan ni oun yoo pa awon eleye, awon eleye ba bere si fi Orunmila se yeye, won fi Orunmila pa miidin. Won ni wipe Orunmila ko gbodo pa awon o. Won ni ti o ba pa awon, egbe awon laye ati lorun yoo ma gbesan awon lo ni o. Eniti o ba ko ile, awon yoo wo. Eniti o ba bi omo awon yoo pa, awon yoo so di alailomo laye. Eniti o ba loyun awon yoo yo je. Eniti o ba ni alaafia awon yoo gba. Eniti o ba n ri se, awon yoo so di alairise. Orunmila ni ki won ma se be wipe awon omo oun po ni ode aye. Won ni ki Orunmila mu apa osi aguntan wa, ki Orunmila toju eku asin merindinlogun, ki o toju oga merindinlogun, ki o toju eso ego, ati opolopo ewe aluki, won ni ki o te ni Osa meji, ki o pe oruko awon mejeje si
.
Monbowa...
Baba e Seun. E jowo e bawa pari ofo yi ki Ise na le pe perepere Eni to ni eni kobunmi eni toni ola kobunmi.....eni toni ojo meje eni kobunmi o ati titilaelae
ReplyDelete