OGUN TI ONISE OWO FI RISE GBA
Ori Okere kan Akere kan ibose Alike Adie Ewe Gbegbe 5. Ose dudu Ao jo gbogbo re papo leekanna pelu Odindin ataare kan ao lo daadaa ao po mo ose dudu, ao ma we ni owuro kutukutu ki orun to yo pelu OFORE RE....
Enu ni
Okere nfi pe olode ninu igbo.. Omo araye ewa pe emi
lagbaja omo lagbaja fun ise mi Enu ni Akere nfi pe omi
we.. Mom araye ema pe emi lagbaja fun ise ti mo nse
Ewe Gbegbe loni ki e ma gbe Ise Kekere owo nla wa fun
emi Lagbaja omo Lagbaja Nitoripe Adiye ki wale ki o mari
ohun ti yio je.... Ao ma se adura to ba wuwa si ao ma pe
ofo yen ti a nba we tested gidi ni
Thank you sir
ReplyDeleteYOUR PHONE NUMBER SIR
ReplyDeleteEseun
ReplyDeleteWhat of someone that black soap those not work on is body nko
ReplyDeleteThank
DeleteThanks alot
ReplyDeleteThank u sir
ReplyDeleteThank you sir
ReplyDeleteThank you sir, pls what is ibose alike
ReplyDeletePlease what's ibose alike sir
DeleteEse pupo sir
ReplyDeleteESE sir
ReplyDeleteThanks so much sir.
ReplyDeleteThanks sir
ReplyDelete