OGUN TI ONISE OWO FI RISE GBA

Ori Okere kan Akere kan ibose Alike Adie Ewe Gbegbe 5. Ose dudu Ao jo gbogbo re papo leekanna pelu Odindin ataare kan ao lo daadaa ao po mo ose dudu, ao ma we ni owuro kutukutu ki orun to yo pelu OFORE RE.... Enu ni Okere nfi pe olode ninu igbo.. Omo araye ewa pe emi lagbaja omo lagbaja fun ise mi Enu ni Akere nfi pe omi we.. Mom araye ema pe emi lagbaja fun ise ti mo nse Ewe Gbegbe loni ki e ma gbe Ise Kekere owo nla wa fun emi Lagbaja omo Lagbaja Nitoripe Adiye ki wale ki o mari ohun ti yio je.... Ao ma se adura to ba wuwa si ao ma pe ofo yen ti a nba we tested gidi ni

Comments

Post a Comment

Popular posts from this blog

OLUGBOHUN NLA EPE ATI ADURA

OGUN ORUKA AWAMARIDI TESO TODAJU DADA